Page
d'accueil Dès que
possible Reprendre une
        vie normale Pulsque vous avez
   posé la question Pensées Autres infos   Page
d'accueil Dès que
possible Reprendre une
        vie normale Pulsque vous avez
   posé la question Pensées Autres infos

Yorùbá

Nipa Wa

Awon Wo Ni SACC?

Awa ni awon owiwosan - dokita, nosi ati awon Olumoran wa.  A ma se eto itoju pajawiri fun awon obinrin, okunrin tabi awon odo mode lati odun mejila soke.  Awon ti agbala baalo tabi to ba in ikom po.  A ko ni davuko enikeui.  Ofe ni gboybo itoju wa.  A ma ntoju awon ti o ba fara pa, a o si pese eniti yi i o se alaye fun wa, ti eni naa o ba le so ede geesi.  E le fi owa kan wa ni igbakigba, tabi ni asikokasiko.  Ti o ba je wipe nkan bi odun meji seyin ni o ti sele, o si le wa ba awon (Counsellor) olumoran wa soro.  A ma se eto ti o ba pe wa si 416-495-2555.


Bawo Ni Mo Se Le Fara Kan Yin?

Lo si ile iwosan ti pajawiri (Emergency Department) ti Grace Division in Scarborough Hospital, 3030 Birchmount Road, Scarborough, Ontario, Canada.  Adugbo Finch Avenue ati Birchmount Road in ile iwosan yi wa.  Ye aworan apejuwe ona ile iwosan wa wo lati le de odo wa.  O si le pe wa in 416-495-2555.


Kilo Ma Sele?

Awon olubewo wa yi o seto ati itoju ti o ba to.  Nwon yi o si pe awon dokita ati nosi ti yi o se itoju ati aajo re.  Nwon a si fi e si iloiti o paroro rinu ile iwosan wa.  Asiko yii in nwon a gbo awon oro ati alaye ti o ba fun nwon, a si se alaye awon nkan ti o le se.  Ti o ba in nkan ti o le ti se eri re, boya bi o ti se fara pa in ti ko si kuro lokan re lati ojo naa.  Nosi yi o se alaye awon ona ti o le gba.  Ti o ba fe fun wa ri gbogbo bi o ti sa sele, a o pe dokita lati be o wo.


Ki Lo Tu Ku?

Ise tiwa ni lati se ise ibewo ati itoju lati owo awon dokita ati nosi ibi ti o ti fi ara pa.  A si ni awon oogun fun arun bi ti arun gbajumo tabi oogun isora fun oyun.  A si ngba awon nkan eri ti o ba fun wa ati awon evi ti awon dokita ati nosi ba ri.  O si le pe eini naa lejo ti o ba fe.


Gbigba Awon Nkan Evi:

A ni awon irin ise ti a le fi gba awon evi ara tabi evi aso re, lati le ran e lowo ni ile ejo.  A le lo awon irin ise yii larin wakati adorin le meji (72 hours) ti isele yii sele si e.  Ti o ba fe ki o di oro olopa tabi oro ile-ejo, a o toju awon eri yii fun bi osu mefa.  Larin asiko yii, o le fi no nkan ti o fe se.  Iwo inkan lo le pase lati fun awon olopa tabi enikeni ni isele yi i.


Ti O Ba Fi Ile Iwosan Sile?

Nosi yi o se alaye in kete kete bi awa aati awon ero okan eniti iru nkan bayi sele si.  Nwon yi o fun o ni oruko awon dokita tabi nosi ti o le pe ati awon itoju ti o to si e.  Nwon a pese eniti yi o se alaye awon olnin ti o le se.  Nosi yi o pe o, lati le se eto itoju ni asiko yi i.


Ti O Ba Fe Ki Elomiran Gbo:

Ti o ba fe ki o di oro olopa, o le se iwe wipe ki o pari si ibe.  Idi ti a ma fi nso fun awon olopa ni wipe ki won ba mo awon ti o ti se iru ese tabi jamba bayi ri.  Won ko ni lo oruko eni ti o sele si.  Iwe ti o ma towo bo wa in ile-ise ti Sexual Assault Care Centre Office.  Awon nosi yi o juwe bi o se le ko iwe yi i.


Eto Itoju:

Ki won fe ipa ba enia sun ki se nkan ti enia le gbagbe lailai.  Nkan to nda enia lokan ru ni, ti o sil nda ironu fun igbese aiye enia ni.  Awon eniti yi o toju e ati awon ora ile re ti wa nile.  Gbogbo awon ara ile re ati awon ore re le wa bawa soro, ki a le mo bi a se le ran awon naa lowo ati bi won ti le se ran e lowo naa.


Eko:

Awon nkan ti o se pataki ni lati pese bi a ti le se se awon alaye ati eto fun awon ile-iwe, ile-ise ati ki awon ara adugbo le mo nipa eto ile-itoju wa, eto bi a se le lo ofin ile-ejo ati bi a ti le se se itoju awa wa.


Ikede Pataki:

O se pataki, a tun ni lati fi si okan wipe, ki i se ebi emiti nkan sele si, sugbon eni ti o se ise janba yi i.

Yorùbá version translated by:
Olutayo O. Agbelusi
Lagos  Nigeria
Flag of Nigeria


The links below have not been translated into Yorùbá at this time.